(S.S. 3:73)
No.
109
Tonic Sol-fa

s: s: d: t: l:
r: d: t: m: r: d:-:
s: m: d: t:- d: r:-:-:
s: s: d: t: l:
r: d: t: m: r: d:-:
r: s:-:-:-

s: f: m: r:. s. s:
f: m: r: d:-:
m: r: d: l:- m: r:-:-:
s: s: d: t: l:
r: d: t: m: r: d:-
d, d, l': f: r:
l:- t: d:-:-:

Ko s’aye f’ọmọ ‘wọ
na n’ile ero
A fi ‘bujẹ ẹran
Ọm’Ọlọrun
ko ni ‘bugbe
l’aye yi
Ko ri ‘bi fori le

Agbelebu nikan
ni wọn fun Krist’
Boji Josẹf’ la sin
Loni O fẹ lati gbe
‘nu ọkan rẹ,
‘wo yo ha wipe
ko s’aye

Yoruba