(S.S. 4.3)
No.
89
Tonic Sol-fa

s: m:. m. m: m:
m: m: m:-: d:-
d: d:. t. d: r: d: l: s:-:-:
s: s:. s. s: s: l:
t: d:-: m:-
m: m:. l. t: d: t:
d: r:-:-:

s: s: l: t: r: m:
r: d:-: s:-
d: f: f: f: f: d:
r: m:-:-:
s. s. d: d: d: d: r:
m: f:-: l:- l. l.
s:. s. s: s: l: t: d:-:-:

Ki ‘hinrere to
de Afrika
Ibọriṣa lo gb’ilẹ kan,
Egun at’ẹṣẹ jẹ ilẹ run
Ṣugbọn ogo ni
f’Ọlọrun

To ran Jesu wa
s’aye ẹṣẹ yi
Lati fi ara Rẹ rubọ
Ki awọn t’o mbẹ
ninu okunkun
Le ni imọlẹ ati iye

Yoruba