(S.S. Bk. 4.24)
No.
82
Tonic Sol-fa

s: m. f. s. m. f:
s: s:-
s: d’. d. d. d. t:
l: f:-:-
f: r. m. f. r. m: f: f:-
f: t’. t. t. l. s:
f: m:-:-

s: m. f. s. m. f:
s: s:-
s: d. d. d. d. d: t: l:-:
l. t. d. t. l. t. d:.
r. m. r. d. l. s:
d: m: d:-:-

Ọmọ ogun Ọba
l’emi
Jesu, Ọba awọn ọba
Ọmọ ogun Ọba
l’emi
Eyi mu ki nma
fo f’ayọ

Mo mba eṣu at’ẹṣẹ ja
Ngo j’onigboya
bi Dafid’
Emi k’yo beru ọta
Nibikibi ti mo
ba nlọ
Ninu ogun Ọba mi

Yoruba