(ACTION 1:40)
No.
36
Tonic Sol-fa

d. r. m: m:
m. f. s: s:
l: m: m: r: d: d:
d. r. m: m:
m. f. s: s:
l: m: m: r: d:-

d. t. l: l:
d: s: s:
l; s, d: d: r: m: s:
d. t. l: l:
d: s: s:
l: s: d: r: d:-

Gbat’O ba de
Gbat’O ba de
Lati ṣir’ọṣọ Rẹ
Gbogb’ọṣọ
Rẹ iyebiye
Awọn ti o fẹ

Bi irawọ owurọ
Nwọn nṣade
Rẹ l’ọṣọ
Ẹwa wọn o
yọ pupọ
Ẹwa f’ade Rẹ

Yoruba