No.
24
Tonic Sol-fa

s: m, m, m, m,
m. r. d. d. t. l.
s. s. l. s. m.
s. l. s. f: r:.
s. l. s. m: d:-

s: m, m, m, m,
m. r. d. d. t. l.
s. s. l. s. m.
s. l. s. f: r:.
s. l. t. d:-:

s. l. s. f: r:.
s. l. s. m: d:.
s. l. d. t. t.
l. l. f: t:
l. s. d. r. m.

s. l. s. f: r:.
s. l. s. m: d:-
l: t. l. t. l.
s: r: d:-:

Awọn ọmọde
ti ongbẹ ngbẹ
li ọna jijin rere
Nfẹ iranwọ
rẹ, nfẹ
iranwọ mi

Awọn
ọmọkunrin
at’ọmọbirin
ni ‘lẹ aṣalẹ
Nfẹ ‘ranlọwọ
l’ọdọ gbogbo wa

Nwọn nfẹ ni Jesu
Nwọn nfẹ ni Jesu
Tani yo sọ
ti agbara
Rẹ lati
gba nila

Kini ‘wọ
yo ṣe,
ki l’emi
yo ṣe
Ki gbogbo wọn
le mọ Jesu

Yoruba