No.
14
Tonic Sol-fa

s. s. d: d:
m. l:. s:-:
m: s: s: r: f: m:-:
s. s. d: d:
m. l:. s:-:
s: s:. s. d: fe: s:-:

t. d. r: r: m: r: s:-:
d. r. m: s:
d: m: r:-:
d. r. m: m:
f: m: l:-:
t. l. s:. l. t: r: d:-:

A gb’ọpagun kan soke
Ọrun ni ile wa
Ogun na nsunmọ tosi
Fun awọn akọni
Ninu ogun mimọ yi
Ọmọ ogun pupọ wa
Ti yo ṣẹgun n’nu Kristi
Lọna opopo Ọba

Yoruba